Moelogo ● WHERE I'M FROM
Want to learn how to sing this song? You can find the Lyrics below to Moelogo's "WHERE I'M FROM" right here on Musik8 -Go To Play-
Olódùmarè
Fi ọkàn mi balẹ̀
Jékín rí je
Rímu
Kín má fi ọwọ́ balẹ̀
Olódùmarè
Òsùbà re mà ré o
Kí...⇣ More
Olódùmarè
Fi ọkàn mi balẹ̀
Jékín rí je
Rímu
Kín má fi ọwọ́ balẹ̀
Olódùmarè
Òsùbà re mà ré o
Kí ọwọ́ ọ̀tá má mú mi
Tí Ire mí bádé o
Hmmm
Hmmmmmmmmm
Hmmmmm
Hmmmmm
Hmmmm
I say hmmmm
Hmmmm
Hmmmm
Hmmmm
I'm too deep
To be mediocre
Moti pẹ́
Bi ti tapioca
Omo opẹ́
I'm so blessed
Bèrè lọ́wọ́ onome
Bó se jẹ́
If I go blame I somebody
Then i hold myself
I was on track but I jonze myself
Mi òlè kan ra m'ọ́lọ́run
Moti gbà fún olọ́run
Pẹ̀lú sùúruuu
I've been looking GOD in the wrong places
Crying out loud
While I burn bridges
Of where I'm from
I know where I'm from
I was lost at sea like old ages
Swimming back
kí ọ́lọ́run shọ́ mi
Délé o
Cause I know
Where I'm from
Olódùmarè
Fi ọkàn mi balẹ̀
Jékín rí je
Rímu
Kín má fi ọwọ́ balẹ̀
Olódùmarè
Òsùbà re mà ré o
Kí ọwọ́ ọ̀tá má mú mi
Tí Ire mí bádé o
Hmmm
Hmmmmmmmmm
Hmmmmm
Hmmmmm
Hmmmm
I say hmmmm
Hmmmm
Hmmmm
Hmmmm
Ẹní bẹ́gi Lójú
Igi árúwẹ́
Orísùn mi màádé
Ẹlẹ́dàá mi ajé
Ibi tí madé madé
I've been looking GOD in the wrong places
Crying out loud
While I burn bridges
Of where I'm from
I know where I'm from
I was lost at sea like old ages
Swimming back
kí ọ́lọ́run shọ́ mi
Délé o
Cause I know
Where I'm from
Olódùmarè
Fi ọkàn mi balẹ̀
Jékín rí je
Rímu
Kín má fi ọwọ́ balẹ̀
Olódùmarè
Òsùbà re mà ré o
Kí ọwọ́ ọ̀tá má mú mi
Tí Ire mí bádé o
Hmmm
⇡ Less
Administrator
Days Ago
Sorry! The Comment Section Was Recently Disabled So You Wont Be Able To Comment on Moelogo's WHERE I'M FROM Track | Song