Want to learn how to sing this song? You can find the Lyrics below to C Blvck's "Omo Aunty Mi" right here on Musik8 -Go To Play-
Ouuhhh
C blvck waddiddoo
Lyrical Mafia
Ẹyin tẹ ti sun lati ọwọ alẹ
Ẹ shiwọ f'alarọ
Haji m'ohun haji mọ voice
Haji lo gbe microphone wọ church (Ouuhhh)
Ọmọ aunty mhi oo keere ninu aye (Ajeh)
Ko easy...⇣ More
Ouuhhh
C blvck waddiddoo
Lyrical Mafia
Ẹyin tẹ ti sun lati ọwọ alẹ
Ẹ shiwọ f'alarọ
Haji m'ohun haji mọ voice
Haji lo gbe microphone wọ church (Ouuhhh)
Ọmọ aunty mhi oo keere ninu aye (Ajeh)
Ko easy k'ọmọ a jẹ pako rale (Oje)
Oo fẹ ṣiṣẹ o fẹ jaye
Oju ẹ a bo bi ẹniti o jo'na mọ'le (Ajeh)
Ọmọ aunty mhi oo keere ninu aye (Ajeh)
Ko easy k'ọmọ a jẹ pako rale (Oje)
Oo fẹ ṣiṣẹ o fẹ jaye
Oju ẹ a bo bi ẹniti o jo'na mọ'le(Ajeh)
Oh pọ ko dun, oh leke nka
Oh dun ko pọ wọn f'oje ka
Aya koto aya kata
Wa pakara ye taraka
Oh pọ ko dun oh leke nka
Oh dun ko pọ wọn f'oje ka
Aya koto aya kata
Wa pakara ye taraka
Oluwa gbemi ga kon she bii ti ladder
Tọn ba nhi ki lon nda k'on she bii ti wákà
Oh maa le k'ẹlẹsẹ toh leh b'alapa ja
Oun gan o nhi fẹẹ gba kanar wọ Canada
On gba lori mhi o da nga já o da o da o da nga ja
Bami w'ọmọ pupa to bah ja fah fah to ba ja to ba ja to ba ja fah fah
Bo'jẹ dudu ab'o ja akata ab'o já akata ab'o já pata
Ologo rainbow wọn lo ja s'ọla o ja s'owo o tun ja s'ọla
Ọ kọ Ọ kọkọ ri kọkọ
Ọ bọ Ọ bọbọ ri bọbọ
Ọ jọ Ọ jọjọ ri jọjọ
Dọdọ yọ wọ'le Ọ gọ gọ ri gọ gọ(Ouuhhh)
Ọmọ aunty mhi oo keere ninu aye (Ajeh) (Gbe gbe gbe gbe gbe)
Ko easy k'ọmọ a jẹ pako rale (Oje) (Kere gbe gbe gbe)
Oo fẹ ṣiṣẹ o fẹ jaye
Oju ẹ a bo bi ẹniti o jo'na mọ'le (Ajeh) (Gbe tan gbe tan)
Ọmọ aunty mhi oo keere ninu aye (Ajeh) (Gbe gbe gbe gbe gbe)
Ko easy k'ọmọ a jẹ pako rale(Oje) (Kere gbe gbe gbe)
Oo fẹ ṣiṣẹ o fẹ j'aye,
Oju ẹ a bo bi ẹniti o jo'na mọ'le (Ajeh) (Gbe tan gbe tan)
Oh pọ ko dun oh leke nka
Oh dun ko pọ wọn f'oje ka
Aya koto aya kata
Wa pakara ye taraka
Oh pọ ko dun oh leke nka
Oh dun ko pọ wọn f'oje ka
Aya koto aya kata
Wa pakara ye taraka
Ẹ máa win oh gara ku
Tẹ ba r'ewe k'ẹ fah kanaku
Moti gbera k'ọta toh laju
Ẹyin Oluwa l'ogo, kẹ s'asalatu
Kọrọ to ya sọn ju titi to tẹh lọ
Wobi ma wo ibẹ ko mọ bi to fẹẹ lọ
Ẹ fun wa nti wa kẹ yọ oun tẹ fẹẹ yọ
Ai jẹbẹ ẹ ti wọ gau ẹti k'ẹran
O leh kuru oo keere
O kan leh tiirin oo benbe
Mo le ku mhi o shere
Toh ba ti d'ọrọ kudi mhi o m'ere
Bọ' bi o waa jo oh eh ke le
Heeehhh oju eh le me le
O gbe yah o gbe yeh
Filẹ f'awọn temi lori keke be
(Ouuhhh)
Ọmọ aunty mhi oo keere ninu aye (Ajeh)
Ko easy k'ọmọ a jẹ pako rale (Oje)
Oo fẹ ṣiṣẹ o fẹ jaye,
Oju ẹ a bo bi ẹniti o jo'na mọ'le (Ajeh)
Ọmọ aunty mhi oo keere ninu aye (Ajeh)
Ko easy k'ọmọ a jẹ pako rale (Oje)
Oo fẹ ṣiṣẹ o fẹ jaye,
Oju ẹ a bo bi ẹniti o jo'na mọ'le(Ajeh)
Oh pọ ko dun oh leke nka
Oh dun ko pọ wọn f'oje ka
Aya koto aya kata
Wa pakara ye taraka
Oh pọ ko dun oh leke nka
Oh dun ko pọ wọn f'oje ka
Aya koto aya kata
Wa pakara ye taraka
Ouuhhh
Ọmọ aunty mhi oo keere
Oo benbe
Ọmọ aunty mhi nhi general Mafia
Emi nhi Lyrical Mafia
⇡ Less
Posted by Bossman
Administrator
Days Ago
Sorry! The Comment Section Was Recently Disabled So You Wont Be Able To Comment on C Blvck's Omo Aunty Mi Track | Song