It's Dtunes again
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
want song, wants favour
e maa ríran wò ti n ba k'orin
mo rí èèmọ l'agege, ajá w'ewu...⇣ More
It's Dtunes again
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
want song, wants favour
e maa ríran wò ti n ba k'orin
mo rí èèmọ l'agege, ajá w'ewu o roṣọ
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
ẹnu ẹni laa fi kọ meejẹ̀
ẹnu ẹni ní power
give me more power, more, more blessings
ti n ba kankun wàá fí fún mi
ìbéèrè mí re o, jẹ o leesi
give me more power, more, more blessings
many wey you don bless, I follow them celebrate
many wey you give power,
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
Iwájú iwájú laa máa máa lo
Aro wa ti weere l'aiye
iwaju ni n máa má lo
lókè, lókè looke ni n máa má lọ
b'ọta mi p'ogun, p'ogbon won lee lasan
iwájú ní n máa má lo
lókè, lókè looke ni n máa má lọ
Iná tí ọmọ oko ya, l'ọmo alè fí sun iṣu je
lókè, lókè looke ni n máa má lọ
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
want song, wants favour
e maa ríran wò ti n ba k'orin
mo rí èèmọ l'agege, ajá w'ewu o roṣọ
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
Iwájú iwájú
iwájú laa máa máa lo
⇡ Less
Administrator
Days Ago
Sorry! The Comment Section Was Recently Disabled So You Wont Be Able To Comment on 9ice's Iwaju Track | Song